 |
EKO EDE YORUBA TITUN- BOOK 1
Author: Atunse Titun, Oyebamiji Mustapha, Oluyemisi Aya Adebowale, Ayo Alagbe, Oyedemi Oyerinde.
Iwe kin-in-ni titi de eketa ninu awon iwe Eko Ede Yoruba Titun, Agbajade otun fun ile eko sekondiri kekere niyi. A se atunse si owo awon iwe yii ni ibamu pelu agbekale korikuloomu titun ti o jade ni odun 2006.
|