Sub Catlog : Eko Ede Yoruba Titun for Senior Secondary Schools| Catalog :Senior Secondary

ẸKỌ ÈDÈ YORÙBÙ TITUN - BOOK 1

Author: Ìwé Kìn-ín-ni, Oyèbámijí Mustapha, Oyèdèmi Oyèrìndé, Ayọ Àlàgbé, Oluyemisi Aya Adebowale.

Ìwé yìí ni èkínní nínú àwọn ìwé ti a kọ fún ọdún mẹta ti ό kẹyìn ní sẹkọndírì. Ìwé náà tanná àkọtun ìmọ sí ẹkọ èdé Yorùbá lóde-òni kedere. Láti ibẹrẹpẹpẹ ẹkọ èdè Yorùbá ni ìwé yìí ti làkàkà láti se àgbéyẹwò ìmọ fonọlọjì, àkọtọ, gírámá, àkàyé, àròkọ àti ìtàn ìsẹdálẹ Yorùbá.


EKO EDE YORUBA TITUN- BOOK 2

Author: Ìwé Keji, Oyèbámijí Mustapha, Oyèdèmi Oyèrìndé, Ayọ Àlàgbé, Oluyemisi Aya Adebowale.

Ìwé yìí ni èkeji nínú àwọn ìwé ti a kọ fún ọdún mẹta ti ό kẹyìn ní sẹkọndírì. Ìwé náà tanná àkọtun ìmọ sí ẹkọ èdé Yorùbá lóde-òni kedere. Láti ibẹrẹpẹpẹ ẹkọ èdè Yorùbá ni ìwé yìí ti làkàkà láti se àgbéyẹwò ìmọ fonọlọjì, àkọtọ, gírámá, àkàyé, àròkọ àti ìtàn ìsẹdálẹ Yorùbá.


EKO EDE YORUBA TITUN- BOOK 3

Author: Ìwé Keta, Oyèbámijí Mustapha, Oyèdèmi Oyèrìndé, Ayọ Àlàgbé, Oluyemisi Aya Adebowale.

Ìwé yìí ni èketa nínú àwọn ìwé ti a kọ fún ọdún mẹta ti ό kẹyìn ní sẹkọndírì. Ìwé náà tanná àkọtun ìmọ sí ẹkọ èdé Yorùbá lóde-òni kedere. Láti ibẹrẹpẹpẹ ẹkọ èdè Yorùbá ni ìwé yìí ti làkàkà láti se àgbéyẹwò ìmọ fonọlọjì, àkọtọ, gírámá, àkàyé, àròkọ àti ìtàn ìsẹdálẹ Yorùbá.