Catalog : Senior Secondary

EKO EDE YORUBA TITUN- BOOK 3

Author: Ìwé Keta, Oyèbámijí Mustapha, Oyèdèmi Oyèrìndé, Ayọ Àlàgbé, Oluyemisi Aya Adebowale.

ISBN: 978 030 086 5

Ìwé yìí ni èketa nínú àwọn ìwé ti a kọ fún ọdún mẹta ti ό kẹyìn ní sẹkọndírì. Ìwé náà tanná àkọtun ìmọ sí ẹkọ èdé Yorùbá lóde-òni kedere. Láti ibẹrẹpẹpẹ ẹkọ èdè Yorùbá ni ìwé yìí ti làkàkà láti se àgbéyẹwò ìmọ fonọlọjì, àkọtọ, gírámá, àkàyé, àròkọ àti ìtàn ìsẹdálẹ Yorùbá.

Iwe yii tun se ayewo lori litireso atenudenu ati litireso apileko yoruba. Orisirisi litireso abinibi ti a ko kọ sile kun aarin awon eya ile Kaaaro Oojire fofofo, iwe yii si jiroro lori pupo ninu won - awon ti won n kewi naa, ohun ti a n ke won fun, asiko ti a maa n ke won ati iwulo won lawujo wa, lapapo, tabi laarin eya kan si ekeji.

Iwe yii ko tun kere ninu titan imole si asa ati ise abinibi Yoruba ati bi asa ati ede se je omo-iya ti ki i ya ara won. Opomulero ni asa ati ede je ninu akitiyan awa eda.

    Write a Comment:

    Name: