Catalog : Senior Secondary
EXAM FOCUS YORUBA LANGUAGE FOR WASSCE & SSCEAuthor: L O Adewole, W O Fatokun, M O Mabayoje, Ore Yusuf.ISBN: 978 030 692 7 Exam Focus Yoruba-Iwe Ifojusun Ajemo-Danwo Ede Yoruba je okan lara awon owoowo akegbe re ti a pile se fun iranlowo awon akeekoo ati asedanwo yoowu-o-je lati koju isoro ti won maa n ba pade nibi idanwo asekagba ti Ajo WAEC, NECO ati Ajo JAMB n se akoso re. Exam Focus Yoruba-Iwe Ifojusun Ajemo-Danwo Ede Yoruba je okan lara awon owoowo akegbe re ti a pile se fun iranlowo awon akeekoo ati asedanwo yoowu-o-je lati koju isoro ti won maa n ba pade nibi idanwo asekagba ti Ajo WAEC, NECO ati Ajo JAMB n se akoso re. Yato si pe a pete ona abayo alailabawon fun awon isoro isowo-dahun ibeere lorisirisi, a se akojo opolopo awose ibeere agbaroko ati apeere idahun won ni eyi ti yoo ran asedanwo lowo nipa sise aseyege alailegbe. Bee naa ni a tun fi opolopo ibeere ewo-ni-dahun ti akekoo le fi gbaradi pelu idahun won sibe. Awon ohun ti a ye wo finnifinni ni ibamu pelu korikuloomu ati silaboosi Ajo WAEC je mo: awon ohun ti ayewe-idanwo-wo n reti lati odo asedanwo, akaye lorisirisi, leta kiko, eto iro ati girama ede Yoruba, iseda oro ati awon ofin ti o ro on, aayan ogbufo, afo asafo ati afo agbaran ati akoto ede Yoruba. Awon onkowe ti won pile se obe yii jinna ti fi igba pupo je olukoni, alamu-imo, ti akekoo le bu mu ninu re pelu aseyege ti o yanju. Won si ti ni opolopo iriri nipa isowo-yewe-idanwo-wo lori ede Yoruba. Idi niyi ti a fi gba pe koseemanii ona abayo ni Iwe Ifojusun Ajemo-Danwo Ede Yoruba yii je fun gbogbo asedanwo. |





Write a Comment: