Catalog : Primary

TAIWO ATI KEHINDE - BOOK 6

Author: Lati Owo, Williams O. Fatokun, Amos G. Ogunwale.

ISBN: 9780307095

Owo iwe Taiwo ati Kehinde iwe Kin-in-ni titi de iwe Kefa ti je ilu mo-on-ka fun awon akeekoo ede Yoruba ojo ti pe. Apilese Otun Keji yii ko sai fo iro ede ti awon akekoo nilo fun itesiwaju eko won lati ibere pepe titi de ipele Kefa eko won si wewe.


Owo iwe Taiwo ati Kehinde iwe Kin-in-ni titi de iwe Kefa ti je ilu mo-on-ka fun awon akeekoo ede Yoruba ojo ti pe. Apilese Otun Keji yii ko sai fo iro ede ti awon akekoo nilo fun itesiwaju eko won lati ibere pepe titi de ipele Kefa eko won si wewe.

Gbogbo imo ti akeeko ipele yii nilo gege bi onimo ede, asa ati litireso, bi i iro ede Yoruba, ifaworan-motumo, ege silebu orisi irin-ise, orisi eewo ni ibamu pelu eko imototo ati bee bee lo ni iwe Apilese Otun Keji yii se akojo won.

Our Primary Titles are UBE Curriculum Compliant:

Aworan lolokan-o-jokan ti o le fa okan akeekoo si eko nipa nnkan ayika eni, eko nipa imototo ati ogooro eko ni ibamu pelu korikuloomu ikoni ni ede Yoruba, ni ipele eko alakoobere ni a ti se afikun re sinu iwe Taiwo ati Kehinde Apilese Otun Keji yii.

se sise ti a fi kun iwe yii fun awon oluko ati obi laaye lati mo boya awon akekoo mo ohun ti a ko won. O si mu irorun ba oluko lati se igbelewon awon akeekoo leyin idanilekoo kookan.

FEATURES OF THE SERIES:

  • Colourful and attractive illustrations are used.
  • Simple and clear language is used.
  • Emphasis is placed on teaching and learning of cultural and moral values.
  • Difficult/new words are explained.
  • Lessons are treated in chronological order as stated in the curriculum.
  • There are footnotes that serve as teacher’s guide.
  • Teaching and learning of mental sum and arithmetic are also included.


    Write a Comment:

    Name: